Yorùbá kìí rìn ìrìn ìdọ̀tí. Yorùbá kìí wọ akisa. Yorùbá lónìí ká wọ buba, ká wọ ṣòkòtò, ká wá gbé agbádá le e lórí. Yorùbá lo ní ká rí ẹni,...
Read More
Home / Yoruba dun
Showing posts with label Yoruba dun. Show all posts
Showing posts with label Yoruba dun. Show all posts

Orúkọ àwọn ẹranko (English and Yorùbá)
Animals and Their Various Yoruba Names ============================= Cobra *** Ọka Ox , Bull *** Malu Spit-Snake ***Ṣebe Dog *** Aja H...
Read More
Wọn ní Tunde tí yà were o: Ẹ wá gbọ ohun tó se
Arábìnrin kan tí ń jẹ Omobaorun Ajibade lọ gbé atejade yìí sórí ìkànnì Yoruba Dun lórí Facebook. "Olorun Koni Je A Kagbako o. Kini k...
Read More
ÒNKÀ YORÙBÁ (YORUBA Counting)
COUNTING – ÒǸKÀ YORÙBÁ ÒǸKÀ YORÙBÁ 1– ọ̀kan/ení 2– m éjì 3– m ẹ́ta 4 – m ẹ́rin 5 – m árùn ún 6 – m ẹ́fà 7 – m éje 8 – ...
Read More
"Mi ò le kọ isẹ ìlù lilu lai ma kọ èdè Yoruba" - Ayantunde Anselm Ramacher omo ilu Germany
Se mo le dupe tan lọwọ Ogbeni Ayantunde Anselm Ramacher ? Ayantunde Anselm Ramacher pelu Olayemi Oniroyin Ti won ba pe eniyan ni...
Read More
Yoruba Dun: Itan igbe aye Olabisi K 39
Yoruba Dun: Itan igbe aye Olabisi K 39 #ayeOlabisiK39 Sii Olootu, Bi awọn eniyan ilu Yoruba Dun ko se jẹ ki Olootu gbadun, bẹẹ ...
Read More
Yoruba Dun: Itan igbe aye Olabisi K (38)
#ayeOlabisiK38 Sii Olootu, Ibi ti mo so itan mi de ni ibi ti awon ẹni ibi yii ti n gbe mi lọ laaarin ọganjo oru. Igba ti won...
Read More
Yoruba Dun: Itan igbe aye Olabisi K (37)
#ayeOlabisiK37 Bi orisiirisii ero se n wa si mi lokan re e. Mi o le so iye ago to lu tori wi pe ko si ina ti mo le fi ri ago ẹgbẹ ogi...
Read More
Yoruba Dun: Itan igbe aye Olabisi K (36)
#ayeOlabisiK36 Inu mi ba jẹ, mo si tun bẹrẹ ẹkun ni sisun. Mo sukun oju mi wu, bee mi o rẹni rẹmilekun. Igba to ya, mo lo fi omi bọ ...
Read More
Yoruba Dun: Itan igbe aye Olabisi K (35)
#ayeOlabisiK 35 Mo ti n ri eniyan laye, ore oko afesona mi tun jomi loju. Gbogbo igba ni o maa n fun mi lówó ki n maa ri ohun ...
Read More
Yoruba Dun: Itan igbe aye Olabisi K (34)
#ayeOlabisiK 34 Sii Olootu, Bi ẹ ko ba gbagbe ibi ti mo ba leta mi de. Mo ti se alaye bi ore mi tuntun ti o je osise ile...
Read More
Yoruba Dun: Itan igbe aye Olabisi K (33)
#ayeOlabisiK 33 Ẹ le ka itan igbesi aye Olabisi K to ti jade tẹlẹ NIBI ki ẹ to tesiwaju lati ka eleyii ki itan naa le yeyin daa...
Read More
Subscribe to:
Posts
(
Atom
)